Olorì Badirat Olaitan, ìyàwó Aláàfin Òyó, Oba Lamidi Adeyemi kékeré, ti parí ifáfitì ní ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Ibadan tí a mò sí University of Ibadan.
Bí omo bá dára ká so, ó ye kí á yé olorì sí lóòótó.
Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...