Home / Art / Àṣà Oòduà / olópàá kan ní Enugu ti mú àwon òdóbìnrin méjì nígbà tí won n rìn l’ójú ònà látàrí aso ìwòkuwò tí won wò.

olópàá kan ní Enugu ti mú àwon òdóbìnrin méjì nígbà tí won n rìn l’ójú ònà látàrí aso ìwòkuwò tí won wò.

Gégé bí eni tí ojú rè to se so, tí ó sì gbe sí orí èro ayélujára se so, olópàá kan ní ìpínlè Enugu ni a ti fi èsùn kàn wípé ó mú àwon òdóbìnrin méjì tí won wò aso ìwòkuwò.
A gbó wípé ìsèlè yí selè ní ojó ajé (Monday), ogún’jó osù kokànlá (November 20) ní òpópónà Garrison ní Enugu.

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...