Home / Art / Àṣà Oòduà / Olojo Ibi Toni – Arabinrin Adetona Banke
olojo ibi toni

Olojo Ibi Toni – Arabinrin Adetona Banke

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Arabinrin Adetona Banke ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata.
Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale okan. Ni oruko Oluwa e o ni ba won na oja warawara nile aye beeni e o si ni dagba yeye, gbogbo ohun rere ti n mu’le aye rorun fun eda ni Eledua yoo fi jinki yin. E o gbo, e o to, e o fewu pari, e o ferigi jobi, e o gbele aye sohun rere bi o ti wa wu ki e pe to laye e o ni f’oju mo saare omo lase Olodumare.
Kabiyesi ati awon Oloye ati gbogbo ebi Omo Yoruba Atata pata nileloko nki yin wipe IGBA ODUN, ODUN KAN NI O.

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti