Home / Art / Àṣà Oòduà / Olùsò àgùntàn tí a mò sí pásítò Adeboye tí ó jé olórí àwon omo léyìn Jésù ti ìjo RCCG fún àwon akékòó ìmò adajó tí ó yege jùlo mérin ní Fìlà orí ri awon adájó àti aso won.

Olùsò àgùntàn tí a mò sí pásítò Adeboye tí ó jé olórí àwon omo léyìn Jésù ti ìjo RCCG fún àwon akékòó ìmò adajó tí ó yege jùlo mérin ní Fìlà orí ri awon adájó àti aso won.

Olórí àwon olùfokànsìn àti omo léyì jésù ti Ìjo àwon RCCG, gbogbo àgbáyé, Pásítò E.A Adeboye fún àwon akékòó tí won sèsè gboyè gégé bíi adájó mérin nínú ìjo rè ní àgbàlá HALL OF MERCY, Bwari ní ìpínlè Abuja, ní èbún.
Nítórí àgbàlá Hall of Mercy yíì kojú da ilé-èkó náà ní, ní Abuja, pasito Adeboye jé kí ó di mímò wípé, enikéni tí ó jé omo àgbàlá náà tí ó se àseyege láti ilé-èkó àwon adájó náa yóò gba àmì èye aso àwon adájó àti fìlà rè.
Àwon olóóri mérin náà ni:
Adewole Oluwatofarati
Ayomide Racheal Akinyemi
Onwioduokit Ugongabasa
Ananyi Emeka Emedo.
Obìnrin méta àti okùnrin kan.

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...