Olúbọ̀bọ̀tiribọ̀
Ẹnu lẹbọ.
Kí là ń bọ nÍfẹ̀?
Ẹnu wọ̀n
Ẹnu wọn là ń bọ nÍfẹ̀
Ẹnu wọn.
Kí ẹnu mi má kó bá mi o
Olúbọ̀bọ̀tiribọ̀
The mouth is an altar of worship.
What is it that we worship at Ife?
Their mouth and tongue
What do we venerate at Ife
Their mouth and tongue
May my mouth not get me in trouble today
~Moyo Okediji
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

