Home / Art / Àṣà Oòduà / Omoge kan ni owó tè tí won sì fi se èsín látárí wípé ó fo odi ilé onílé láti jí bisikitì .

Omoge kan ni owó tè tí won sì fi se èsín látárí wípé ó fo odi ilé onílé láti jí bisikitì .

       Ònlò èro ayélujárá ( Facebook) tí a mò sí Arc Pashal Chike Umeobi ló so wípé arábìnrin yí ni owó àwon figilanté tè ní Ezinifite , ìlú kan ní ìpínlè Anambra .

Arábìnrin yí ni won fi èsùn kàn wípé ó fo odi ilé láti jí ìpápánu tí a mò sí bisikitì ni owó pálábá rè bá ségi nígbà tí ìkan lára àwon figilanté ri wípé ògbòn n rùn, figilanté náà bá gbìyànjú àti mu sùgbón tí ó bó, ó sì yìn ìbon lùú tí ó sì yè é n ló bá tún fo odi ilé míràn láti balè nínú ilé onílé míràn ,kíá ni onílé yára figbe bonu, béè ni owó bá tè é….

About Awoyemi Bamimore

One comment

  1. Hardeymorlar Tozyne Thosco

    Haha……. O mu bisikiti, Haa……Ebi n pa niyen, Se ko jin pure water ni. (Olee……….)

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti