Home / Art / Àṣà Oòduà / Omobìnrin kékeré yí ni won dáné sun nígbà tí won fi èsùn kàn án wípé àjé ni, ní ìpínlè Akwa Ibom.

Omobìnrin kékeré yí ni won dáné sun nígbà tí won fi èsùn kàn án wípé àjé ni, ní ìpínlè Akwa Ibom.

Àwòrán tí ó wà ní ìsàlé yí ni àwòrán omobìnrin kan tí orúko rè a máa jé Queen, won dáné sun omo yí látàrí èsún tí won fi kàn án wípé Àjé ni.

Anja Louvre tí ó jé panépané ní ìpínlè Akwa Ibom ní ó gba omobìnrin yí kalè, tí kò sì jé kí ó kú ikú òjijì.

Ó gba omobìnrin yí kalé kí ó tó di wípé ó gbé èmí mì nígbà tí àwon èèyàn rè dáné sún ún ní ó kojá odún kan séyín.

Arábìnrin òsìsé Danish yí ni ó pín àwòrán yí sí orí èro ayélujára rè, tí ó sì ko isé tí ìgbìmò won n se síbè, nígbá rí ó jé wípé ètó won ni láti ran àwon lówó bí ti Queen.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti