Àwon ebí akékòó bìnrin kékeré tí ó sonù láti bí ojó mélòó séyìn ni a ti gbó wípé arákùnrin kan ni ó wá gbe ní ilé-èkó léyìn isé òòjó náà .
Omobìnrin tí ó jé akékòó ní ilé-èkó Okpe grammar school ní Sapele ní ìpínlè Delta ni won ri wípé kò wálé ti won sì ti wa kò sí ilé-èkó rè sùgbón tí won kò rì.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


