Home / Art / Àṣà Oòduà / Omokùnrin Wizkid , Ayo kékeré òun àti ìyá rè múra jáde nínú aso orílé èdè Nàíjíríà .

Omokùnrin Wizkid , Ayo kékeré òun àti ìyá rè múra jáde nínú aso orílé èdè Nàíjíríà .

    Binta Diallo àti omokùrin rè ,king Ayo kékeré jáde lo láìpé tí won sì tàn gan nínú Dashiki won àti aso orílè èdè Nàíjíríà. Aso orílè èdè Nàíjíríà yí jé kí ó dà bi omo Yorùbá tí ó gba okàn obìnrin kan ….

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

iwure tooni

#Iwure Owuro Tooni lati enu Kolawole Ifarotimi

Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...