Home / Art / Àṣà Oòduà / Òòsà Roman lo sí ibi ayeye ìgbéyàwó alárédè ti Oritsefemi àti ìyàwó rè, Nabila Fash, níbi tí ó ti wo aso tí àyà rè hàn.

Òòsà Roman lo sí ibi ayeye ìgbéyàwó alárédè ti Oritsefemi àti ìyàwó rè, Nabila Fash, níbi tí ó ti wo aso tí àyà rè hàn.

   Gbajúgbajà tí olórun fún ní èbùn tí ó bùáyà, tí a mò sí òòsà obìnrin ti ilè Roman lo sí ibi ayeye ìgbéyàwó alárédè ti Oritsefemi àti Nabila Fash pèlú àyà rìwòwò tí olórun fún lo sí ibi ayeye ìgbéyàwó ìbílè Oritsefemi ní Lekki ní ìlú Eko.

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Omisore

Àwàdà kẹrí-Kẹrì ni àwọn kọmití tó ní mi ò lè díje du ipò gómìnà APC ni 2026 n ṣe – Omisore

Yínká Àlàbí Awọn kọmiti to n ṣe àyẹ̀wò awọn oludije du ipo gomina labẹ ẹgbẹ́ oselu APC ti ja igbakeji gomina tẹlẹ ni ipinle Osun, Alagba Iyiola Omisore ati awọn mẹfa miiran.Wọn ni iwe wọn ko pe lati dije du ipo gomina ipinlẹ naa. Awọn mẹfẹẹfa to ku naa ni – Babatunde Oralusi, Oyedotun Babayemi, Dr. Akin Ogunbiyi, Benedict Alabi, Adegoke Rasheed Okiki, ati Senator Babajide Omoworare.Iyiola Omisore ni awada Kẹri-Kẹri ni awọn kọmiti naa n se nitori ti wọn ...