Home / Art / Àṣà Oòduà / Òrékùnrin mi ń bínú sími.
divorce

Òrékùnrin mi ń bínú sími.

E jòwó, mo fé àmòràn lórí ohun tí ó ye kí n se, osù kewàá rèé tí mo ti mo Òrékùnrin mi, a sì ní ìfé ara wa, sùgbón Òrébìnrin rè télè sì ń dàá láàmú, èyí sì ń jé kí n jowú.

No wá gbèrò láti sí èro ayélujàra (facebook) míràn pèlú àmì ìdánimò míràn, mo bèèrè lówó Òrékùnrin mi bóyá ó ma so òtító, sùgbón ní tòótó ó so òtító nípa rè, mo wá ń bú Òrébìnrin télè rè yí pèlú èro ayélujàra (facebook) tuntun yí sùgbón àsírí padà tú sí Òrékùnrin mi yí lówó wípé èmi ni mò ń se gbogbo èyí, báyìí kò fé fé mi mó to rí wípé mo ti ni í lára púpò jù, mo tún wá ń bú Òrébìnrin rè télè yí.

Mo ti bèé sùgbón ó ya elétí ikún, kò yé mi mó, nítorí mo ní ìfé rè pèlú gbogbo okàn mi. E jòwó kí ni mo le se?

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti