Home / Art / Àṣà Oòduà / Oritsefemi dòbálè ní iwájú àwon àna rè, àwon òbí Nabila Fash níbi ayeye ìgbéyàwó ìbílè won.

Oritsefemi dòbálè ní iwájú àwon àna rè, àwon òbí Nabila Fash níbi ayeye ìgbéyàwó ìbílè won.

Oritsefemi àti àwon òré rè ti dòbálè níwájú àwon ebí ìyàwó rè tí a mò sí àna rè níbi ìgbéyàwó náà, ìgbéyàwó náà dára púpò.
N se ni ó dàbí kí èmi náà lo se ìgbéyàwó báyìí.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti