Ọbàtálá ọbátárìsà
Ọba pátápátá tí ń bá wọn gbóde iránjé
Ọba nílé Ifọ́n
Ò sùn nínú àlà
Ò jí nínú àlà
Ò tí inú àlà dìde
Òrìṣà wun mi ní budo
Ibi Ire l’òrìsá kalẹ
Akú òsè Obàtálá O
Pages: 1 2
Éèpà ÒrìṣàMo ṣẹbà aṣẹ̀dá!Mo ṣèbà Ọba àlà funfunỌba ńlá o jíreWa túnbọ̀ tàlà bòmí,Àlábàláṣẹ! Happy Ọbatala worship day Obatala #Oriṣanla #Ancestor #Yoruba#Decolonization