Home / Art / Àṣà Oòduà / Ose tu’a
Babalawo Ifakayode Ajani

Ose tu’a

ko-mi-koro awo Ewi l’Addo
Orun koko-ko awo Ijesa m’Okun
Alakan nigbo ‘do t’eye ifá kerekere-kere
adi’a fun Igba Irunmole ajikotun
obu okan fun Igba Imole ajikosi
alukin fun Orunmila
nijo ti won ti Isalu orun bo wa Isalu aiye
Eledumare niki won ma fi imo je Osun
Orunmila nikan ni O fi imo je Osun
aseyinwa aseyinbo Osun ma bi o bi Osetura
Ara yio tu gbogbo wa loni Ase
Ire o!

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti