HUN !!!
Otito wa da bi Akisa Elegbin ni niwaju
Oluwa …
WOO ORE WA !!
Bawo lo se roo pe o mo (mi) to…
Nje iwo ri ara re gege bi Ododo loju
gbogbo aye ?
Se iwa re lo dara julo ti o n ri ara re gege bi
Ayanfe Olorun ?
GBOMI DAADAA ORE WA !!
Bi Oluwa ba nse Amiwo Ese ni.
Taa lo le duro niwaju ite Olodumare ?
Orun nikan lo mo eni ti yoo la
Kosi Saka lara da ninu eda niwaju
Oledumare
DAKUN ORE WA !!!
Ma ri enikan gege bi Olori Elese
Eledua nikan lori Koro koowa..
TORIPE
Eniyan n woju…
Olorun mi a si maa wo Okan.
A KU OJUMO..
A ku Ojo Isinmi (SUNDAY) Tonii
Opo Alayo iru-e la o dijo maa se loke Eepe.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

