HUN !
B’o ti wu ki a pe laye to …
A pee lorun ju bee lo…
::::
WOO ORE WA !
#Igba o lo bi #Orere..
Bee, #Laye taa wa yii ko lo bi #Opa_ibon
:::::::
DAKUN ORE WA !
So igba-meta yii ninu Ayee re ::
Igba #Bibi
Igba #Dida
Igba #Dide
…….
#IGBA_BIBI : ni aye ti eda nlo lati igba to ti
bawon ke mowa-mowa sile aye;; igba yii
nikan nigba aimo
…
#IGBA_DIDA : ni aye ti eda nlo leyin igba
aimo mo re; Ti eda n rokan #kin_laa_da ??
Laye leyin jije,mimu,nina,lilo…
……
#IGBA_DIDE : ni aye eda ni igba-ikeyin aye re,
Ti o yeki Eda maa beere lowo araa re wipe
#Nibo_ni_maa_de_si ?? Leyin isemin aye mi…
::::
AKIYESI KAN REE O :: Kii se gbogbo Eda ni
igba meteeta yii maa nba laye idi niyi ti o
gbodo ronu piwada lonii bi o se nfi oye gbe
#OUNJE_EMI_TOORO_YII je .
::::::::
A KU OJUMO
#Oni a sanwa s’owo, S’omo, S’alaafia ati
Aiku-baale-oro lase eledua
Tagged with: Àṣà Yorùbá