Home / Art / Àṣà Oòduà / Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún.

Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún.

Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún.
Olùsó Daniel Udoh, tí ó dá ilé ìjosìn “Agbejórò ni jésù” sílè ni owó sìkún ìjoba ti tè ní Akapabuyo, ìpínlè Cross river látàrí fífi tipátipá bá omo rè obìnrin odú méje lòpò.
Udoh ni won ti fi sèsín káàkiri pèlú àwon mókàndínlógórin(79) elésè míràn ní Calabar.
Omo rè wà ní ilé-ìwòsàn tí ó n gba ìtójú lówó fún ìjàmbá tí ó selè si.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

masoyinbo

#Masoyinbo Episode Seventy-three: Exciting Game Show Teaching Yoruba language and Culture