Home / Art / Àṣà Oòduà / Owó✋lá fi n sisé owó
owo

Owó✋lá fi n sisé owó

Esè la fí ñ rìnnà Olà
Àtowó àtesè ki Elédùmarè má gba ìkankan nínú rè lówó wa, ká lè fi rí nñkan Ajé kó jo…

Asáré pajé
Arìngbèrè polà
Òhun ewà ní wón jó n wòlú
Adífáfún Ògbìngbìn kan Ògbìngbìn kàn
Tó re inú ìrókò lo ree múlé si
Tó n polówó ajé tantantan.
Ó ní Alájé eni kìí la, kínú ó bínii
Ñjé kí là ñ jé lótù Ifè tájé fi n yale ëni?
Ògèdè òmìnì là ñ jé lótù Ifè tájé fi nyale eni ..

*Lónìí tí osù tuntun bèrè, Ajé yó fi ilé gbogbo wa se ibùgbé ooo… Àse..*

*ooduarere kí i yín, wípé a kú osú tuntun Ooo*

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti