Foto tuntun Diezani Allison-Madueke ni yii, minisita fun epo robi nigba kan ri, eni ti won fesun jegudujera kan niluu London. Won ni ara madaamu naa ko ya rara. Joojumo si ni ipo ilera re n buru sii. Arabirin naa niidi adura bayii, ki Olorun alaanu ba wa da alaafia pada si lara. Ase !
Olayemioniroyin.com
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

