Sineto Musiliu Obanikoro ti lo kí Oònirìsà .
Sineto Musiliu Obanikoro tí ó jé adarí àwon olúdábòòbò ti orílè èdè Nìjíríà télè ti lo kí baba wa Oònirìsà tí a mò si àrólé odùduwà ní ìlú ilé-ifè ní ojó mélòó séyìn.
Èyí fi hàn wípé kò sí bí èèyàn se le tó Oba ba lórí ohun gbogbo, bí ó ti le wú kí ènìyàn bí olá tó Oba ni oba yóò máa jé.
Obanikoro dòbálè tán pátápátá fún baba wa Adeyeye Enitan Ogunwusi. Àwòrán rèé ní ìsàlé.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

