Home / Art / Àṣà Oòduà / Sùúrù lógbà.

Sùúrù lógbà.

Ìsé kìí se ohun àmúseré
Ìyà kìí se ohun àmúsàwàdà
Ebi ń pamí kìí mérìń p’ani
Sebí ebi kìí w’onú
Kí òrò míràn wòó

Ojú tí ń kúkú pón isin
Kìí se àpón ku
Bí kòse àpónlà
Bówù kópé títí
Ìyà ayé eni ń bò wá d’ópin
Sùúrù tó kúkú l’ójó ni

Àforítì ló kúkú se pàtàkí
B’órí bá pé n’ílè á kúkú d’ire
Sùúrù lógbà

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti