Home / Art / Àṣà Oòduà / Tánkà tí Ó gbiná ní ànà tí Ó sì pa òpò èèyàn.
bulava

Tánkà tí Ó gbiná ní ànà tí Ó sì pa òpò èèyàn.

Ní déédé agogo márùn-ún ìròlé àná ni ìjàmbá ńlá tí Ó tún jé mánigbàgbé fún orílè èdè Nìjíríà selè, nígbà tí Tánkà ńlá kan gbiná ní ojú pópó ònà tí ó wà láàrin ìlú Èkó si Ìbàdàn.

Òpò àwon èèyàn ni ókú tí àwon kan sì fi ara pa, ti Òpò okò sì sègbé.
Ó mà se o àfi kí olórun gbà wá ní orílè èdè yí.

Kí elédùmarè té àwon tí Óní kú sí aféfé rere.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti