Home / Art / Àṣà Oòduà / Tuface àti àwon omo rè okùnrin méjì Nino àti Ziona Idibia ní New York.

Tuface àti àwon omo rè okùnrin méjì Nino àti Ziona Idibia ní New York.

Tuface àti àwon omo rè okùnrin méjì Nino àti Ziona Idibia ní New York.

Gbajúgbajà tí ó tún jé ògbóntarìgì olórin ìgbàlódé ti a mò sí Tuface Idibia tí ó wà ní orílè èdè United State báyìí fún ìrìn àjò rè ni ó ya àwòrán pèlú àwon omo rè okùnrin méjì tí ó jo ó bí ìmumu, Nino àti Ziona tí won jo jáde pò ní ìpínlè New York.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti