Ojà tí ó wà ní ìlú Abeokuta ní won tì pa pátápátá ní àná, won se èyí láti fi se àpónlé Oba won tí ó wàjà eni tí a mò sí Oba Halidu Laloko (MFR) tí ó jé Agura ti Gbagura tí ó papòdà láti lo bá àwon baba ńlá rè ní ojó kejìlá osù keje odún 2018 (12/07/2018).
Èyí fi hàn wípé Àsà Yorùbá kò le parun.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

