Home / Art / Àṣà Oòduà / ‘Yee! Yee!! Ni gbogbo n ke’
oriki

‘Yee! Yee!! Ni gbogbo n ke’

Basẹ ba mumi
Omi a tan ninu asẹ,
Bígèrè ba mumi
Omi a tan ninu ìgèrè,
ko tan ko tan lajá á lami;
Ó tán n bí ò tàn?
A ráta, a rata, ata kan ojú,
ata n tani bi ata.
Ata kuro lorẹẹ o dọta àtàtà.
‘Yee! Yee! yeee!’ ni gbogbo n ke.
Orile yii Dàdán,
Abi ko Dàdán?
”Eniyan to loun o fọ ibajẹ –
aye yii mọ,
Oluwa rẹ o kan Iyọ ninu ìdin”.

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti