Home / Art / Àṣà Oòduà / Zion Ayo Balogun ; Wizkid so omo rè okùnrin tí Jada pollock bí fún ní orúko.

Zion Ayo Balogun ; Wizkid so omo rè okùnrin tí Jada pollock bí fún ní orúko.

   A gbó láìpé la gbó wípé Wizkid ti kí omo tuntun káàbò tí alákoso rè, Jada Pollock bí fun. Òótó ni èyí, Wizkid ti ri dájú wípé omo òun ni , ó sì ti so omo náà l’órúko “Zion Ayo Balogun”.

A kí o kú oríre starboy, kí ire náà kárí.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti