Home / Art / Àṣà Oòduà / Ki lo sele si Taiwo leyin iku Kehinde Osuolale (Ibeji Oran)?
ibeji oran

Ki lo sele si Taiwo leyin iku Kehinde Osuolale (Ibeji Oran)?

Leyin odun kan ti Kehinde Osuolale dagbere faye, iroyin mi-in tun ti kan wa wi pe ikeji re, Taiwo naa ti lo ba ikeji re lajule orun.

Ohun ti a gbo ni wi pe ilu Abuja ni Taiwo ku si.

Titi di akoko yii, Olayemi Oniroyin ko ti le so pato boya otito ni isele nigba ti iwadii si n tesiwaju.

About admin

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

1472 lagos

Is Oyo an Oppressor or a Protector? | How the Portuguese Arrival in Lagos in 1472. £P1.