Awon omo egbe apapo-Yorùbá-titi eka –oselu, Afenifere ati awọn omo egeb (Oodua Peoples Congress), OPC, ti fariga nipa rogbodiyan ti oun lo ni ilu Ile Ife. Ninu oro kan ti abenugo fun eggbe Afenifere kán so eyi ti un se ogbeni Yinka Odumakin wipe, opolopo dukia ni o sonu ati emi awon ana ise ni won pe ati wipe pupo ninu awon ti awon agbofinro mu ni ki un se alaise aye won sọnu ni figagbaga ṣugbọn faulted aabo operatives fun rù jade a ọkan-apa imuni ti diẹ ninu awọn alaiṣẹ olugbe.
Ninu oro won afenifere sọ pé: opololopo awon ti awon agbofinro mu ni alaise eyi ti won ko lo si ago olopa ni ilu Osogbo ati ago won ti o wa ninu Abuja. Ba kan na olori awọn omo egeb (OPC), Otunba Gani Adams ti pe ipe fun pele larin awon ara ilu Ile Ife ati awon Hausa na lati ma gbe ni aalafia .
Ninu oro kan nipa awọn alabagbe yi , akowe ti OPC ogbeni Yinka Oguntimehin sọ pé: “A ko fẹ ki alejò ti oun gbelori ilewa so wa di eni ti a o beru lori ile babawa. Awọn Yorùbá ko ni gba lati je eni ti won yi o ma beru ni ori ile won abi lati je eru ni orílẹ-èdè yi . O te se wa ju ni oror re pe ki won tu awon ti agbofinro mu lala ise se le ni waran sesa, Ba kan na ni ogbeni ti oruko re unje Babajide Omoworare, omo ile igbimo aso fin agba titi olu ilu ile wa ti o wan ni ilu Abuja ti o nsoju (Osun East Senatorial District ni National Assembly) nigba ti o sabewo si Sabo ni bi ti awon awusa na un gbe ni ile ife Omoworare tun so wipe oun o fe ki itaje sile wa larin awon husa ati ara ilu ile ife mo, bee na ni o pese iranwo fun awon ti won padanu dukia ati ounje.
Awon igbimo apapo the (Supreme Council for Sharia in Nigeria SCS) ti eka oriilede nigeria ti fi da awon orinide yi loju wipe won yi o wa unkan se si rogbodiyan na lati mafa gbonmisi omioto kakiri orile-ede yi.
English Version:
Continue after the page break.