Soldiers take over Abuja for President Jonathan’s declaration tomorrow. Abuja is going to be shut down for the event.
Àwo̩n S̩ó̩ò̩sì bè̩rè̩ ìjó̩sì l’Abuja lónìíYínká Àlàbí O le ni osu meji bayii ti ijoba apapo ti fofin de Soosi ati Mosalasi. Ijoba ni ki onikaluku maa josin ni ile won, ijoba ni ko si ibi ti Olorun ko si ati wi pe Olorun sun mo wa ju isan orun wa lo.Eyi lo mu ki gbogbo ile ijosin wa ni titi pa. Ijeeta ojo jimo, ojo karun-un, osu kefa yii ni ijoba apapo ni ki awon Mosalasi gbogbo ni ilu ...