Igbakeji Aare ile Naijiria nigba kan ri, Alaaji Atiku Abubakar ti ro ijoba to wa lode yii, eleyii to wa lowo egbe oselu APC, lati je ki eto eko ofe ti won se ileri re kari gbogbo eka ikekoo patapata, bere lati alakobere titi to fi de ileewe giga.
Oro yii lo jade lenu Turaki gbogbo Adamawa nibi ayeye odun kewaa ti won ti da American
University of Nigeria sile, eleyii to kale silu Yola.
Atiku, Aare Adimula ti Ile-Ife, ni orileede yii ko kare to nipa sise itoju awon olopolo ti Edua oke fi jin-inki wa nipa eto eko to yanranti lateyin wa.
Ninu oro apileso oro Aare egbe akekoo School of Hygiene tilu Kano lodun 1967, eleyii ti akori re je: “Beyond Terrorism: The need for Education reform”, Atiku gba egbe All Progressives Congress, APC, niyanju lati ri iyipada to waye nipa olusejoba gege bi anfaani lati mu atunse deba isakoso orileede yii to ti mehe seyin.
Bakan naa, Oko Titilayo Albert Abubakar ko sai gbe oriyin fun Buhari latari igbiyanju ati ise takuntakun re lati mu opin deba awon alakatakiti esin Islam ti won je Boko Haram.