Home / Art / Àṣà Oòduà / Sofia Kenin gba ife è̩ye̩ ìdíje Australia open 2030
Sofia Kenin

Sofia Kenin gba ife è̩ye̩ ìdíje Australia open 2030

Omo orileede American, Sofia Kenin, ti fi ebun re han si gbogbo agbaye pelu bi o se bori ifigagbaga asekagba laarin oun ati omo orileede Spain, Garbine Muguruza pelu ami ayo 4-6 6-2 6-2 ni Melbourne lati gba ife eye idije naa ti abala awon obinrin.

Eyi ni igba akoko ti Garbine, odun mokanlelogun, yio gba ife eye naa leyin igba mejila otooto ti o ti n kopa sugbon Muguruza ti gba ife eye naa ni igba meji otooto.

Kenin ni agba eyin orile obinrin ti okere julo lati gba ife eye Australia Open leyin ti omo orileede Russia, Maria Sharapova ti gba ni odun 2008.

Se Yoruba ni won so wipe inu eni o ki fun ki a pa mora ! Kenin, eni ti o je wi pe baba re ni olukoni re, le opa igba eyin orile re mole ti o si fo mo baba lorun lati fi idun re han si aseyori alailegbe naa.

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Quadri Akinade Aruna vs Hugo Calderano

Quadri Akinade Aruna vs Hugo Calderano | MS R16 | WTT Finals Men Doha 2023