Láìpé yí ni Davido pín sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram láti pín àwòrán àti ìtàn ti tàtúù tí ó sèsè yà sí apá tí ó pè ní “30BG” kí ó tó di wípé ó fé se ...
Read More »Cee-c pèlú Toolz àti Yaw.
Ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Cee-c ti ya àwòrán pèlú Yaw ti Wazobia FM àti Toolz ti Beat FM lénìí nígbà tí won se àbèwò sí won.
Read More »Omobìnrin tí won ti ń wá láti ojó mélòó séyìn, èyí tí ó fi ilé-èkó sílè láti tèlé Òdókùnrin kan ní ìpínlè Delta.
Àwon ebí akékòó bìnrin kékeré tí ó sonù láti bí ojó mélòó séyìn ni a ti gbó wípé arákùnrin kan ni ó wá gbe ní ilé-èkó léyìn isé òòjó náà . Omobìnrin tí ó jé akékòó ní ilé-èkó Okpe grammar ...
Read More »Ilé-ìwòsàn àwon ará Sokoto .
Ilé-ìwòsàn àwon ará Sokoto . Ìyá yí pọ̀ Ó ju omi òkun lọ Èdùmàrè Ìwọ tó o dá Ráábí aláṣọ Dákun má gbàgbé Ráábí eléwé Èdùmàrè ṣàánú mi Iná tó ń jó tálákà ní Nàìjíríà Ó dájú pé ó ju ...
Read More »Omo ìbàdàn
Omo ìbàdàn Ìbàdàn mèsi ògò, n’ílé olúyòlé. Ìlú ògúnmólá, olódò kèri l’ójú ogun. Ìlú ìbíkúnlé alágbàlá jáyà-jáyà. Ìlú Àjàyí , ò gbórí Efòn se fílafìla. Ìlú Látóòsà, Ààre-ònà kakanfò. Ìbàdàn Omo ajòro sùn. Omo a je ìgbín yó, fi ìkarahun ...
Read More »Omo Ibadan ati Ankara Gucci !
Oríkì ìbejì
Oriki Ibeji: Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí ...
Read More »Owe Toni: Lati Owo Jude Chukwuka
Ìfé Mi (My Love)
Ìfé Mi (My Love) Eni bíi okàn mi Adúmáradán orenté Olólùfé mi àtàtà Ìfé re ní n pa mí bí otí òyìnbó Lá ì gbó ohùn re Mi ò lè sùn mi ò lè wo Léyìn re kò sí e ...
Read More »ORÍLÈ ÈDÈ MI
ORÍLÈ ÈDÈ MI Nàìjíríà ìlú mi pàtàkì Ìlú t’ókún fún ogbón Pèlú òpòlopò àwon òjògbón Ilé ogbón Tí a ti n hun àgbòn ìwà ìbàjé S’ogúndogójì di ààyò àwon òdó Òsèlú di ohun wón k’èyìn sí Egbé òsèlú di ìkan ...
Read More »