Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 41)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Odunlade Adekola ti parí ìdánwò è ní UNILAG.

   Gégé bí ó ti pin sí orí èro ayélujára (Instagram). ” Nígbà tí o bá parí ìdánwò, tí o wá n padá li sí ilé , tí o wá kó sínú súnkere fàkere oko, wà sà ya àwòrán, mo ...

Read More »

Ààre Buhari lo rí àwon omo egbé CAN ní ilé ìgbìmò ní ìlú Abuja.

   Ààre Muhammadu Buhari ti lo rí àwon omo egbé Christian Association of Nigeria (CAN ) ní ilé ìgbìmò ní ìlú Abuja.

Read More »

À n yan Àntà ( alligator ) tí a pa nínú oko ìresì wa.

   Ìsinmi tòtè yí mà yàtà gan o, ó ti è ti dùn jù …járá oko yí mà da gan ni oo . Àwòrán obè aláta yéríyérí n bò láìpé.

Read More »

Òdóbìnrin ni ó ya àwòrán orúko Runtown gangan sí ìdí rè.

    Níbáyìí, ojú wo ni òrékùnrin rè ma fi wò ó tí ó bá rí ìdí òdóbìnrin yí?. Àwòrán tí ó ti gba èro ayélujára kan ni ti obìnrin tí ó ko orúko Runtown gangan sí ìdí rè. Olórin ...

Read More »

E wo ejò tí aládùúgbò mi pa, e jò wó kíni orúko rè.

   Aládùúgbò mi ló pa ejò nlá yí ní kùtùkùtù òwúrò àná … Oúnje ti se.

Read More »

Laura Ikeji Kanu tún yo ní àrà òtò.

  Onísòwò aso àti olù gbé eré jáde, Laura Ikeji gbé lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tí ó ya ni lénu yí.

Read More »

Àwòrán ayeye ìsìnkú Obi Madubogwu.

  Akoni òsèré , Obi Madubogwu tí ó kú ní ojó kejìdínló’gbòn osù kejo ( 28/8) nígbà tí ó jèrora ìtò súgà fún bí odún díè séyìn ni won ti sin sí ìlú rè ní Ogidi ìpínlè Anambra. Gbajúgbajà òsèré ...

Read More »

Ajé omo Olókun.

   Òrìsà ni olókun jé, a gbó wípé òun ni ó bí ajé, ó tún jé òrìsà orò àti ti ìsàlè òkun. Olókun ni ó n darí omi ó sì ní àse l’órí gbogbo ìsèdá inú omi . Olókun máa ...

Read More »

Nnamdi Mpiti tí ó jé akunjú (make up artist) pín àwòrán yí .

   E má jé kí èrù bà wá . Kíkùn lásán ni , àti wípé èjè iró ni ó wà níbè “.

Read More »

Àwòrán tí Tonto Dikeh àti Halima Abubakar yà tí won sì rewà nínú àwòrán náà.

  Òsèrè orí ìtàgé, Tonto Dikeh gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà yí tí òun àti òré rè tímótímó , òsèré Halima Abubakar yà.

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb