ko-mi-koro awo Ewi l’Addo Orun koko-ko awo Ijesa m’Okun Alakan nigbo ‘do t’eye ifá kerekere-kere adi’a fun Igba Irunmole ajikotun obu okan fun Igba Imole ajikosi alukin fun Orunmila nijo ti won ti Isalu orun bo wa Isalu aiye Eledumare ...
Read More »APINTANBI
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun Ku isimi opin ose eledumare koni jeki a fi eleyi se asemo o ase. Laaro yi mo fe so die nipa oro APINTANBI ti awon opuro ati ...
Read More »Isu Oro bale ro pee…
A da fun eji, ti o ma bowo fun iko Odidere, won ni ko kara nile, Ebo ni ko mu se. Ojo o ni ro ko pa ina iko Odidere, Iko Odidere d’Orisa. Ni Agbara Olodumare ati oruko Orunmila, Gbogbo ...
Read More »Otura Oriko, wa lo ree silekun ire temi fun mi! Aase!
Hoje também é dia de propiciarmos Olokun. Que a força e o Ase de Olokun abra as portas do progresso e da prosperidade a nossa família criando condições para que todos os obstáculos sejam retirados de nosso caminho. Ikan lowo ...
Read More »Ewe Yi Je Òkan Lara Awon Ewe Ifa To Dara Pupo
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku isimi opin ose, emin wa yio se pupo re laye ase. Laaro yi mofe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi lati inu odu ...
Read More »Atitare/Itare: Pataki ewe towa ninu aworan yi ninu odu ifa OTURA ORILANA
Aku ise ana o oni a sanwa o, aanu olorun Olodumare koni fiwa sile loni o ase. Laaro yi mofe ki e mo Pataki ewe towa ninu aworan yi ninu odu ifa OTURA ORILANA, ati iwulo e ti o se ...
Read More »Kini oruko ewe yi ?
Ejo kini oruko ewe yi
Read More »Kereyale / Yale – Iwulo Ewe To Wa Ninu Aworan Yi
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a san wa sire gbogbo, bi odun yi se ntan lo akoni fi aisan pari re lase eledumare ase. Laaro yi mo fe ki a mo iwulo ewe ...
Read More »Oruko wo ni ama pe awon to’n diru’n nilé Yoo’oba ?
E ba mi dahun ibeere yii
Read More »Bi Ere BI Awada Oorun Odun 2016 n lo Ibi Ati Wo….
Ni iru akoko yi opo ile ise nla nla ni won ngbaradi ati se akosile asekagba ise iriju won fun odun ti nlo sopin yin… Beeni opo osise ile ise wonyi ti a ti fun ni gbedeke nibi ise won ...
Read More »