HUN !!! Otito wa da bi Akisa Elegbin ni niwaju Oluwa … WOO ORE WA !! Bawo lo se roo pe o mo (mi) to… Nje iwo ri ara re gege bi Ododo loju gbogbo aye ? ...
Read More »Ogbon O Di Igi A Fi Okun(Rope) …
Ojulu, ti opo-eniyan bama wi won a ni ogbon o di igi a fi okun(rope) won a tun ni kosi abuja(short-cut) lorun ope, sugbon ogbon di igi fun eni ti eledua ba gbon, be sini abuja ‘be lorun ope ti ...
Read More »Olojo Ibi Ti Oni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa Omolola Adex ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata. Maami Olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re ...
Read More »Ire ni mo ko
Ire ni mo ji ri Ire tororo d’ori awa o Ire toorun ogberi o mo o Aase IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole
Read More »Ritual painting of ORÍ
photo credit – Michelle Ifayemisi Sangofunmilayo McCollin
Read More »Iwure owuro 26.07.2016
*Aje ko ni di ota a mi. *Edumare dakun fidi aje sole nile mi. *Imo ota, imo elenini ko ni se lori mi. *Emi ko ni di eni arisa ati arisunkun. *Edumare fi aso iyi wo mi(Ase). Aare Olasunkanmi Alani ...
Read More »Baba Oloye ifayemi Elebubon: E ku ojo ibi
Ododun ni sapo nruwe,ododun leruwa,bi odun bajo peregun a mu awo tutu de, Baba ara Ododun lee Mon be. E ku ojo ibi baba Oloye ifayemi Elebubon.
Read More »Ore yeye Osun!
May we all be blessed today and beyond. Ore yeye Osun! Take it to the river. Ore yeye Osun! – – –
Read More »Iyawo tagbe wani ojo aiku mati soro, egbo bose wi
Olotu: ekasan ooo eyin ara ile,asiku asiko yin, eledua yowa pelu gbogbo wa o,ase. Iyawo tagbe wani ojo aiku mati soro egbo bose wic….Gbogbo eyin ebi mofe ki e fi ise yin bura fun mi pe ti moba so e ...
Read More »Abi e roju aye bi?
Orewa nso fun ara ile wipe ki won Ba oun gbe orin, sugbon won o da loun, lo ba binu lo Si oko o da orin sugbon won o fun lounje, o tun lo si Odo o da orin won ...
Read More »