Yoruba dun-un ka yoruba e komo yin o, ko tun le ko ko tun le so ede abinibi. A~ AJA, B~ BATA, D~ DOJE, E~ EJO, E~EYE, F~ FILA, G~ GELE………. A B D E E F G GB H ...
Read More »Foto: Ara Kenge !
E bami kira fun Ife….gbosa, gbosa, gbosa
Read More »Orin, Owe ati Ewi !
ORIN : ” Ododo-Eye mi, ko ma re danu .. Ko maa re danu, Loju aye mi.. Ile nimo ko o, Oko nimo ra.. Omo,Omo l’adele o… …… OWE : * Agba waa bura bewe o ba se-o ri. * ...
Read More »Iwure Owuro 28.05.2016
E MAA WI TELE MI : ………… *Edumare fi aanu re wa mi ri. *Oluwa s’ekun mi d’erin. …… *Edumare koni fi omo pa mi lekun *Ododo/Omo mi ko ni re danu. *Emi ko ni di arisa fun omo mi. ...
Read More »Idile Alayo: E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. ...
Read More »Ounje UNJE Eme Fun T’ooro Yii – 26.05.2016
HUN ! B’o ti wu ki a pe laye to … A pee lorun ju bee lo… :::: WOO ORE WA ! #Igba o lo bi #Orere.. Bee, #Laye taa wa yii ko lo bi #Opa_ibon ::::::: DAKUN ORE WA ...
Read More »Orunmila Declared: Sooner or Later
The Ori of the rat will lead the rat to the correct ath The Ori of the Awo will lead the Awo to the path of success Sooner or later, the Ori of the fish will lead the fish to ...
Read More »Odo Iwoyi – 2
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. ...
Read More »Eeto Owe L’esin Oro – 3
A ku deede asiko yii o ni aafin ilumoye, moki gbogbo wa kaabo si akotun eeto yin, eeto wa OWE L’ESIN ORO, oro l’esin owe ti oro ba sonu owe ni a o fi waa jade. Ope nla lo si ...
Read More »Ogulutu Oro Toni – 24.05.2016
Wo binu ba nbio masoro, tinu re basi ndun mase ile ri, fi eniyan buburu sile saye re. # wo Mase mura lati gbija arare fija le f’OLOHUN,ohun nikan loba elesan….. Ire oo
Read More »