Eku Dede asiko yio eyin eniyan Atata tin GBE inu ilu Yoruba Atata, oro tonlo Lowo bayi ni mo muwa oro elo obe to won gogo yi ma ni mofe kia soro Lorie o. E wo tomato timo ra ni ...
Read More »Ibeere Toni: 15.05.2016
Nje Iwo leso “FACEBOOK PASSWORD” re fun Ololufere????? Huuum ema paro ooo
Read More »Arewa Asa Toni: Afeez ati Mide Martinez Abiodun
Ko so’ogun mo bee si ni ko so’ote mo ni igbeyawo eleyi ti o ku die ko dojubole. Oserekunrin Afeez Abiodun “Afeez Owo” ati iyawo re Oserebinrin Mide Martin ni ti mu ife won padabo sipo. Laipe yi ni edeaiyede ...
Read More »Iwure Owuro: 14-05-2016
E MAA WI TELE MI : ….. *Fitila ogo mi ko ni ku. *Aso iponju ko ni se dede orun mi. *Oluwa ba mi segun ota ile. *Edumare ba mi segun ota ode. *Ina omo ko ni jo mi. *Ina ...
Read More »Ogulutu Oro Toni: 08.05.2016
Hummm wo oremi banuso mobayan so tori inu jin. # wo Opolopo ore lo nfara han gegebi ota Oplopo ota naa losi nfi ara han gegebi ore….. # nje Otie mo pe opo alangba lo dankun dele ao kuku mo ...
Read More »Iki’Ni Fun Ayeye Ojo Awon Iya Wa
ORIN : “E bami KIRA fun #Mama mi.. #Orisa bi #IYA o.. Ko si Laye… …………….. Iya mi.. Abiyamo lojo Ogun le.. Abiyamo Oloja Aran Abiyamo tii fojooumo wa ko le Dara fun Omo… …………………… Ki Emi gbogbo Awon #IYA ...
Read More »Iwure Owuro: 08.05.2016
E MAA WI TELE MI : …….. *Oluwa gba eru iya lori mi. *Edumare ma se je ki n seru egbe. *Oluwa taari alaanu si mi. *Edumare fiso re so mi. *Oluwa pase irorun sinu aye mi. *Iku aitojo ko ...
Read More »Sun re o: Francis Aiyegbeni alase ‘D’Rovans Hotel’ ni ibadan
ojuluoooooooo! owe ni oro-aye, A NLO SI OYO O KOJU SI OYO A TUN BO LATI OYO OYO NAN LO TUN KOJU SI. SE BI ILU-GANGAN. iyen nipe ORUN LATI WA ORUN NAN LAO PADA SI. iku pa ABIRI o ...
Read More »The voice of Olodumare in Holy Odu, Odi Meji. Ifa ni
A ku Ose o! Ifa a gbe wa! Bawo l’oni? Apa aja jagada nii mu’ na; Bawo l’ola? Apa aja jagada nii mu’ na; Olokose funfun, irere idi re funfun; Lo difa fun Ogbegbe ranyinranyin; Ti n loo fi ese ...
Read More »A Young Iyalorisa Tells Us The Role Of Dance and Song In Yoruba Spirituality
My name is Egbelade Omitonade Ifawemimo. I practice African Traditional Religion, Yemoja worshipper. I am Yemoja priestess which also versed in Ifa, Researcher, Theologian. I am a graduate of Obafemi Awolowo University where I studied Economics Education, Ile Ife, Osun ...
Read More »