Minisita fun eto ilera, Ojogbon Isaac Adewole, ti se idaniloju alaye wi pe, efon abami ti n sokunfa kokoro Zika ti ko gboogun ti wa ni Naijiria. Bakan naa lo si ro awon eniyan lati se ohun gbogbo ni ikapa ...
Read More »
ayangalu Comments Off on “Efon ti n fa kokoro Zika wa ni Naijiria, kosi ti gboogun”- Minisita Ilera
Minisita fun eto ilera, Ojogbon Isaac Adewole, ti se idaniloju alaye wi pe, efon abami ti n sokunfa kokoro Zika ti ko gboogun ti wa ni Naijiria. Bakan naa lo si ro awon eniyan lati se ohun gbogbo ni ikapa ...
Read More »ayangalu Comments Off on Bayii ni a se le se iwosan fun eni to ni kokoro inu eje
Awon ohun elo ti a gbodo wa ni yii: 1 Omi osan wewe igo kan tabi oti igo kan tabi omi grape igo kan 2 Capsule red & yellow eyo mewaa (10 pieces) 3 Ewe taba ti won ti ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ewu to wa ninu foonu lilo ati pataki ilera wa
Opolopo wa ni a n lo foonu ni aye ode oni, sugbon ti a kosi mo awon ewu keekeke to ro mo o eleyii to le se ipalara fun ago ara wa. E je ka ri daju wi pe a ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwosan ogbe inu
Awon nnkan won yii lo maa n se okunfa ogbe inu; ki eniyan maa fi ebi pa ara re nigba gbogbo, jije ounje gbigbona ati iyo pupo ninu ounje ati bee bee lo. Bi a se maa se iwosan naa ...
Read More »admin Comments Off on E jowo eyin, abiyamo, e dakun e gba wa ni imoran ..
OOOOOOO Oro naa ti di lbanuje ati edun okan fun molebi mi, e dakun e gba mi ooooo. Mo je Omo odun metadinlogbon (27 years) Taiwo. . . . . . ni Oruko mi, Okunrin ni mi, bakan naa ni ...
Read More »admin Comments Off on Awon agbejoro tuntum ti ogbeni saraki sese GBA ni yi o
Ejowo kini oruko won ?
Read More »BalogunAdesina Comments Off on Sisi ologe elo ni Suru ooo
Se Eledumare to da IDI yin bi o se mon IDI kaluku yin se ko se da ni in? Awon kan wa sese ma lo ogun abi abere. Se ni tori iranu yi na E wo won oooo. Awon kan ...
Read More »admin Comments Off on Awise Awo Agbaye Wande Abimbola
admin Comments Off on Eyin ojogbon eniyan, kini itumo awon oro won yii ?
Enikan lo lo ki ore re,ko si ba ore re nile, sugbon o ba okan ninu awon omo ore re nile. Oni baba re n ko? Omo naa ni:”Baba mi lo so okun (rope) aye ti o fe ja” Iya ...
Read More »admin Comments Off on
Enikan lo lo ki ore re,ko si ba ore re nile, sugbon o ba okan ninu awon omo ore re nile. Oni baba re n ko? Omo naa ni:”Baba mi lo so okun (rope) aye ti o fe ja” Iya ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more