Arábìnrin yí ni ó jí èro ìbánisòrò ogbòn (30) tí ó sì ko pamó sí inú kómú àti pátá rè. Odóbìnrin tí a kò mo eye tí ó su ú, ni ó jí ju èro ìbánisòrò ogbòn lo tí ó ...
Read More »Nabila Fash kúnlè Oritsefemi oko rè nígbà tí ó fón Dólà si l’ára ní ibi ayeye kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won.
Nabila Fash kúnlè Oritsefemi oko rè nígbà tí ó fón Dólà si l’ára ní ibi ayeye kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won. Ìyáwó Oritsefemi, Nabila, wà ní orí ìkúnlè níwájú oko rè nígbà tí ó bá Dólà fun níbi ...
Read More »Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ológun yí àti òdóbìnrin tí ó pàdé lórí èro ayélujára (Facebook) ya.
Isé rí èro ayélujára n se kojá òye èdá… Àwon oko pèlú Aya àfésónà yí ti setán láti di tokotayà ní òsè péréte si léyìn tí won làdé lórí èro ayélujára (Facebook). Gégé bí Ijeoma Nwosu se so, ó ...
Read More »Flavour àti àwon omo rè obìnrin méjì, Sophia àti Gabrielle Okoli ti ya àwòrán tí ó ya ni lénu .
Gbajúgbajà olórin ìgbàlódé èyí tí a mò sí Flavour ti gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán àwon omo rè tí ó pè ní olorì, nígbà tí ó se ayeye ojó ìbí rè pèlu Sophia àti Gabrielle.
Read More »Àwòrán Yvonne Nelson àti Jamie Roberts, bàbá omo rè níbi tí won tí n fi ìfé hàn sí ara won.
E wo àwòrán èyí tí ó fi ìfé hàn láàrin olólùfé méjì, ògbóntàrigì òsèré orílè èdè Ghana Yvonne Nelson pèlú bàbá omo rè tí ó jé ayà àwòrán láti orílé èdè Britain. Jamie Robert wo okò òfuruufú láti lo ...
Read More »Omobìnrin kan ní ilè Akwa Ibom ni àwon ebí rè ti fi sílè fún ikú sùgbón olùrànlówó kan ti gbà á kalé.
Àwon òsìsé tí ó ranilówó láti orílè èdè Denmark àti olùdásílè ètò ìsàkóso àwon èwe (Children’s Aid Education and Development Foundation (ACAEDF), Anja Ringgren lovên, ti ran omobìnrin odún méwàá lówó, omo tí a mò sí Deborah, èyí ...
Read More »Arákùnrin kan ní Bayelsa ti se oúnje sí eran Anta tí ó pa.
Arákùnrin kan tí ó wá láti Yenegoa ní ìpínlè Bayelsa, Bogilizibe Godwin Obiene, ti gbèrò láti se obè aláta yéríyérí abó kan léyìn ìgbà tí ó pa eran afayàfà tí ó je. Arákùnrin tí inú rè n dùn yí pin ...
Read More »Funke Akindele ti ya àwòrán tuntun.
Gbajúgbajà òsèré obìnrin orílè èdè Nàíjíríà, Funke Akindele ti gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tuntun ti ara rè tí ó sèsè yà níbi tí ó ti padà sí enu isé. Sùgbón ìbéèrè ni wípé, sé ...
Read More »Àwòrán tí Annie Idibia yà tí ó tún yo ní àrà òtò nínú aso ìbílè tí ó wò tí ó sì se ara l’óge.
Òsèré obìnrin orílè èdè Nàíjíríà tí ó tún jé ìyàwó 2baba tí ó jé olórin nlá, olorì Idibia dàbí egbin lo sí ibi ìgbéyàwó Banky W àti Adesua ní ojó ìsinmi tí ó kojá. Mo dàgbà tán èwe wù ...
Read More »Oba ti ilè Benin, Ewuare,ti kalè sí Abuja pèlú àwon olóyè rè fún àbèwò pàtàkì.
Oba ti ilè Benin, Aláse èkejì òrìsà, Oba Ewuare ti balè sí Abuja fún àbéwò pàtàkì. Oba tí àwon olóyè rè sìn lo sí Abuja ni won ti kí káàbò, àwon alága ìgbìmò egbé APC (All progressive Congress), John Oyegun ...
Read More »