Photo Cc- Iyalaje Fama
Read More »Ogulutu Oro Toni – 27.08.2016
Hummm bona kan o badi odamiloju pe ona Miran olela,iyen fun enito ba mo nkan ti nse. Woo Orewa Benikan ba sope sise re titan lodo ohun, mofe komope ose tie ni kose ti Olohun o, nise ni kode fila ...
Read More »Ìfẹ́ láàárín ara wa
Ìfẹ́ láàrin ara wa Ìfẹ́ dára, Ìfẹ́ dùn bí a bá pàdé oní tí wá, Ìfẹ́ jẹ́ òhun tí ó má ń ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn ènìyàn, Yálà ọkùnrin sí obìnrin, Obìnrin sí ọkùnrin, Ìyá sí ọmọ, Bàbá sí ọmọ, Ọkọ ...
Read More »Ìtẹ́lọ́rùn – #Ìtẹ́lọ́rùnṣepàtàkì.
Ìtẹ́lọ́rùn ni baba ìwà, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe pàtàkì fọ́mọ adamọ, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe kókó, A gbọdọ̀ ni ìtẹ́lọ́rùn, Kí a le rí ayé gbé, Kí a le gbáyé ìrọ̀rùn, Aìní ni ìtẹ́lọ́rùn le mú ni jalè, Bí ohun tí a ni kò ...
Read More »Aṣọ wíwọ̀
Èèyàn lèyí ni àbí wèrè? Asínwín lèyí ni àbí abugije? Ṣé aṣọ lèyí abi kini? Ha! Ayé tí bàjé, Gbogbo ọmọ adáríhunrun tí sọ àṣà nù, A gbé òmíràn, A fi aṣọ sílè láìwọ̀, A sọ ìhòòhò rí rìn di ...
Read More »Ìfẹ́ – Èyí wa fín àwọn olólùfẹ́ láti fi ranse sí olólùfẹ́ wọn
Ẹyín féràn ẹnu,ofi ṣe ilé, Irun féràn orí ,ofi ṣe ilé, Ìràwò òwúrò tèmi nìkan, Olólùfẹ́ mi, Nínú aba ayé yìí Ẹkuro emi mi alabaku ẹwa rẹ, Ọrọ ìfẹ́ yi n yimi Mo ni mi o nífẹ̀ẹ́ mon, Ife ìwọ ...
Read More »#Òmìnira
Òmìnira ṣe pàtàkì, Òmìnira ṣe koko fún gbogbo ohun Òlódùmarè dá, Bí ènìyàn bá nínú ìnira tàbí ìgbèkùn, Tí ó wá rí ìtúsílẹ̀, Àyípadà rere a dé, Ìfọ̀kàbalẹ̀ á wà, A bọ lọ́wọ́ ìdarí ọ̀gá, A bọ nínú wàhálà ...
Read More »Ogboni – Isese Lagba
EEPA MOLE !!!
Read More »ARUGBA is no longer a Virgin maid
Arugba is not only seen as a virgin maid any longer, she is regarded a goddess herself and people make prayers and cast all their problem on her as she bears the calabash and passes on to lead the people ...
Read More »Isese la wa nbo n’Ife ka to rire(Ogunderin)
It is Ancient Religion we worship in Ife, the cradle of Yoruba Religion, before we receive goodness . It started in 1987 when some enlightened people such as Oloye Sola Atanda, Asiwaju Awo Agbaye Ile Ife, Late Wale Egberongbe, Dr. ...
Read More »