Olotu:kini ikan tori tofi ni o le gba ki iya gbe pelu re,gbogbo awon eyan loti ba e so,o ko,o loni gbo,won tun gbe e wa sori afefe,agidi yi nan lotun lo.Kini ikan to sele gan. Iyawo:seri olotu,mole gba ki ...
Read More »
ayangalu Comments Off on Iyawo: mi o le gba ki iya oko mi gbe pelu mi lailai.
Olotu:kini ikan tori tofi ni o le gba ki iya gbe pelu re,gbogbo awon eyan loti ba e so,o ko,o loni gbo,won tun gbe e wa sori afefe,agidi yi nan lotun lo.Kini ikan to sele gan. Iyawo:seri olotu,mole gba ki ...
Read More »ayangalu Comments Off on Olojo Ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alfa Ola Akeem Totofun’un ti won je okan pataki ninu ebi Ooduarere. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ojumo Ire
B’ojumo ba mo .. Ooye a la #peregede.. A D’ifa fun Peregede tii se yeye #Ojumo . A KU OJUMO #Ojumo to mowa Lonii. #Ojumo_Ire gbogbo ni yoo je funwa lase Oba mi Oke .
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure owuro ojo oni 17/07/2016
E maa wi tele mi : *Edumare pese owo irorun fun mi. *Edumare dakun faanu wa mi ri. *Edumare ma fi mi daamu aye. *Eleda a mi ma faye daamu-un mi. *Ogun roju je roju mu koni je temi *Egun ...
Read More »ayangalu Comments Off on Elesin Oyan
Iba Orunmila Bara Agbonniregun; Elesin Oyan; Adagbaa Ojomu; Gbolajoko Omo Ere l’apa; Baba Okinkin ti n m’eyin erin fo; Odudu tii du ori emere ti o je ko fo; Atori eni ti ko sunwon se! Iba Baba o!
Read More »ayangalu Comments Off on Feeling lonely does not mean that you are alone
It just means that you have others around you that do not share the same emotions. Loneliness can be felt even if you have people around you. It is the emotional loneliness that makes you sad. But now you have ...
Read More »ayangalu Comments Off on Oniwowo ado! Baba dakun ma na mi o! Aase!
OBALUAYE!!!!!! OOOOOOO cc- Babalawo Ifakayode Oyedele Osaifa
Read More »ayangalu Comments Off on Foto ode’oni – 13.07.2016
Saheed osupa akorede ati baba wande.
Read More »Edakun kini oruko olorin yii
Read More »ayangalu Comments Off on Lakinni Ajakinni Ajinni…
Lakinni Ajakinni Ajinni, Oba ma pe mo pe o loruko, nigbati oju pon Alara, Alara pe o loruko, odi eni ajiki. Lakinni Ajakinni Ajinni, Oba ma pe mo pe o loruko, nigbati oju pon Ajero, Ajero pe o loruko, odi ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more