Òdóbìnrin àtúnbí yí ti sí tàtúù apá rè pèlú irin gbígbóná.
Òdóbìnrin àtúnbí tí ó jé omo orílè èdè Nàíjíríà, ti jó owó rè pèlú irin gbígbóná ní èróngbà láti pa tàtúù owó rè, gégé bí ó se so wípé èsè ni , ó sì le dínà láti wo ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Òdóbìnrin àtúnbí yí ti sí tàtúù apá rè pèlú irin gbígbóná.
Òdóbìnrin àtúnbí tí ó jé omo orílè èdè Nàíjíríà, ti jó owó rè pèlú irin gbígbóná ní èróngbà láti pa tàtúù owó rè, gégé bí ó se so wípé èsè ni , ó sì le dínà láti wo ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán tí ó yanilénu tí Empress.
Njamah òsèré Nàíjíríà, Empress Njamah tí ó kò láti ní adé orí , látàrí wípé ó ní owó lówó gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà ti ara rè. Òsèré yí dàbí eni tí inú ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Fayose se ayeye odún ketàdínlógóta (57)ojó ìbí rè pèlú ìsìn ìdúpé ní sóòsì pèlú ìyàwó rè.
Gómìnà ìpínlè Ekiti Fayose se ìsìn ìdúpé ní gbàgede Lady Jibowu ti ilé ìjoba fún ti ayeye odún ketàdínlógóta ojó ìbí rè. Àwòrán ibi tí ó ti n dì mó ìyàwó rè.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Òbísúárì okùnrin kan, ìyàwó rè pèlú omokùnrin won tí a gbó wípé won sin won ní ojó kan náà .
Oun tí ó ba ni nínújé gbáà ni ìsìnkú okùnrin kan pèlú ìyàwó rè àti omokùnrin won tí ó kú ní ojó kan náà. A gbó wípé ojó kan náà ni won ma sin wón ní ìpínlè Imo. Èyí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ère Nana Akufo- Addo ni Rochas Okorocha fé sín ní Imo.
Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha ti se tán láti sín ère ààre Nana Addo ti Ghana ní Owerri nígbà tí ó ti sí ère ti ààre Ellen Sirleaf ti Laberia àti Zuma ti South Africa . Ère náà ti ...
Read More »Lolade Comments Off on What good things can you say about Naija?
As a North American who has spent over a decade in Nigeria, I realized I should state this publicly more often because I think it most every day: Nigeria is f***king amazing. Nowhere else can one test the boundaries of ...
Read More »BalogunAdesina Comments Off on Syrian War Report – November 16, 2017: Fierce Fighting Erupts In Eastern Ghouta
On November 15, Ahrar al-Sham officially declared a start of the operation to capture the Armored Vehicle Base and the nearby area from the Syrian Arab Army (SAA) in Eastern Ghouta near Damascus. Ahrar al-Sham, Hayat Tahrir al-Sham (formerly Jabhat ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Destiny Etiko wo sòkòtò bénbé pèlú aso yí ó ba mu.
Òsèré Nàíjíríà tí a mò sí Etiko Destiny ti jáde láì wo Kómú. Òsèré yí wá gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tí kò wo Kómú yí.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Gómìnà Obaseki se ayeye odún kan tí ó ti dé ipò, Akeredolu àti Amaechi náà sì ba yò.
Gómìnà ìpínlè Ondo, Akeredolu lo bá Gómìnà ìpínlè Edo se àjoyò odún kan tí ó dé ipò ní pápá Samuel Ogbemedia, Benin city.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more