Home / Art / Culture / Ẹ̀rìndínlógún !

Ẹ̀rìndínlógún !

Ẹ̀rìndínlógún
Èjì Ogbè

Ogúnlénírinwó okọ́
Ọ̀tàlélégbèṛin àdá
Wọ́n dárí jọ
Wọ́n ń lọ bókè jagun
Òkè kò jẹ
Òkè kò mu
Òkè ni yíò ṣẹ́tẹ̀ gbogbo ajogun.

Twenty and four hundred hoes
Sixty and eighty hundred machetes
They conspired
And launched a war against Oke, the Hill
Oke does not eat
Oke does not drink
Oke will defeat the plot of all malevolent forces

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kínni Ifá wí?" (What did Ifa say?)

Divination “Kínni Ifá wí?” (What did Ifa say?)

Medium: Ballpoint pen on paper