Anthony Joshua ní láti gbáradì fún ogun míràn báyìí ni Alibaba tí Ó jé apanilérìn-ín àti adérìn-ín pa òsónú se so nígbà tí Anthony fi aya rè hàn tí èyí sì fi hàn wípé okùnrin mésàn-án ni, òun náà sì ya àwòrán ara rè hàn wípé kí Anthony Joshua gbáradì nítorí òun yóò se tán títí odún méjì.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

