Home / Art / Àṣà Yorùbá / Asiri àwo kintú,
Asiri àwo kintú1

Asiri àwo kintú,


Asiri ẹ̀tú kintú, 
Iwọ iwori bógbè IFA, 
Ki owá bo asiri mi
Iwọ iwori bógbè.

Mogbá ládùrá wipè loni ọjọ àbámẹtá asiri gbógbó wa koni tu kotobó lailai,gbogbo abá ti aba da loni yio jẹ mimusẹ, 
Aṣẹ̀ aṣẹ̀ aṣẹ̀.


Aṣẹ̀ aṣẹ̀ aṣẹ̀.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ mi: Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ !

Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ Ènìyàn ò daWọ́n lè sọ́ sómi Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun tòní wípé kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ èmi àti ẹ̀yin, Ọlọ́run ọba kò ní fí le ọ̀tá lọ́wọ́ o. Kọ́kọ́rọ́ Ayọ̀ wa kò ní bọ́ só mi. Àsẹ