Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwọn agbẹjọ́rò ta ko ìnáwó àti òfin kó-nílé-ó-gbélé Ààrẹ àti àwọn gómìnà
court

Àwọn agbẹjọ́rò ta ko ìnáwó àti òfin kó-nílé-ó-gbélé Ààrẹ àti àwọn gómìnà

Orisiirisii awon agbejoro ati awon amofin pelu ojogbon lorisiirisii ni won ti n yo suti ete si igbese awon ijoba orileede yii, paapaa julo lori arun coronavirus to gbode.


Won ni ko tile tona rara ki ijoba apapo dede kede ki-onile-o-gbele lai fi to awon ile igbimo asofin kekere ati nla leti. Won ni eleyii lodi patapata si ofin ile wa ti odun 1999.

Won ni bi a si ti n towo bo owo ilu naa maa leyin nigba ti arun yii ba lo. Won ni ko tun ba ofin ile wa mu rara. Won ni loooto ni isuna wa fun nnkan ojiji sugbon ijoba apapo ati ijoba ipinle ko tile tele okankan alaale awon ofin naa.

Ara awon agbejoro naa ni a ti ri Ebun-olu Adegoruwa (SAN), Inibehe Effiong, Charles Omole lati U K ati bee bee lo. Eyi si n fa ariyanjiyan pelu awon ojogbon kookan, awon ni ko si iye ti ijoba apapo ati ti ipinle na ti o po ju ti iru ajakale arun yii ba sele.


Àwọn agbẹjọ́rò ta ko ìnáwó àti òfin kó-nílé-ó-gbélé Ààrẹ àti àwọn gómìnà
Ìròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19

Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19Yínká Àlàbí Ajakale arun ti gbogbo eniyan ro pe ko ni pe fi orileede yii sile, lo ti ko ti ko lo mo yii. Eyi lo wa bere si ni ko gbogbo aye lominu paapaa orileede Naijiria. Awon ajo NCDC to n gbogun ti arun coronavirus pokan po lati wo bi won se le fi owo ile too. Ajo awon onisegun ibile parapo, won sin pa itu meje ti ode n ...