Home / Tag Archives: omo oodua

Tag Archives: omo oodua

kini oruko kokoro yii

Gege bi Omo Oodua Rere, Nje E Mo Oruko ti won pe kokoro yi ?

Kini Oruko ti won pe kokoro ti o wa ninu aworan oke yii ?

Read More »

Òṣèré wo ni ẹ fẹ́ràn jù nínú àwọn àgbà osere meji yi?

Read More »
oodua

Oòduà Words Of the Week

Báyií – This is how, Báwo? -How? Bákan – Somehow, Bádé – Arrived withBálo =Go withBárò =Commeserate

Read More »

Adanwo ni oro ile aye: Iku Abubakar Audu gba arojinle

Titi di akoko yii, enikeni ko le so pato ohun to sekupa oludije ipo gomina labe egbe oselu APC ni ipinle Kogi, Abubakar Audu. Se ise aye ni abi amuwa Olorun oba? Ohun ti ko ye enikan, kedere ni niwaju ...

Read More »

Iru ere wo gan loyan la yo nigba ewe re ?

Omo Oodua rere ajirebi? Iru ere wo gan loyan la yo nigba ewe re ? (1) Bojuboju (2) Bokoboko (3) Ekun meran (4) Suwe (5) Tete (6) Ere toko ti iyawo

Read More »