Ojó tí a ti n retí ti pé o! Ebuka pín àwòrán aso tí wò lo sí #BAAD2017 tí ó túmò sí Banky Adesua 2017. Níbi tí ó ti fi ara rè hàn. E wo bí gbajúgbajà yí ...
Read More »Monthly Archives: November 2017
Maggi Anwuli Oputa: Nwa nwanyi nwa nwoke Charly onye bu Onye newulite anu aru ma burukwa nne nke umu asaa.
Maggy Anwuli Oputa bu nne nke umu asaa mana anuaru ya adokachala, O bu onye newulite anuaru. Nna ya Charly Nwoke, Onye bu nna Ogbe, Kere foto Maggy na asomumpi nke ndi newulite anuaru we dee Ihe a: Adaeze ...
Read More »Arábìnrin tí ó n gba ààwè funfun fún Wizkid láti ségun àwon òtá rè.
Odóbìnrin kan ní orílè èdè Nàíjíríà, Bosslady ni orúko rè n jé ní orí èro ayélujára (Instagram) ti jé kí ó di mímò wípé òun n gba ààwè funfun fún Wizkid, nítorí bí ó se so ó ní Wizkid ní ...
Read More »Èmi ni mo ko àkosílè orin tí Davido sèsè ko tí ó n jé “like that” Teni tí ó jé adá ni lára yá , Teniola Apata.
Olórin kan ní orílè èdè Nàìjíríà adá ni lára yá Teni ti pin sí orí èro ayárabíàsá (Twitter) láti fi hàn wípé òun ni òun ko àkosílè Orin tí gbajúgbajà olórin Davido sèsè ko, ó ní òun ni òun ...
Read More »Jude Okoye tí ó jé ègbón àwon psquare ti rò wípé àsìkò ti tó kí òun sòrò lórí Aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè.
Ó ti dá àwon olólùfé won lóhùn lórí èro ayélujára (Instagram), Jude Okoye ti fi ogbón sòrò nípa aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè tí ó sí wípé òun kó ni olórí ebí won. Ó ko síbè wípé. ...
Read More »Okò tí ó gbé epo petiírólù àti okò èrò ni ó kolu ara won ní Orlu Imo, ogbòn èèyàn ni ó kú.
Ìjàmbá nlá ni ó selè ní orí afárá (bridge) tí ó gbajúgbajà ní Njaba lónà Umuaka – Okwudor ní ìpínlè Imo. Gégé bí ìròyìn se so okò epo petiírólù àti ti gáàsì tí ó kolu bóòsì elérò méjìdínlógún ní Orlu, ...
Read More »Odóbìnrin àgùnbánirò tí ó jé omo odún mérìnlélógún (24), ni won sin ní ìpínlè River.
Ojó díè séyìn ni won pín ìròyìn burúkú tí ó selè sí omo odún mérìnlélógún yí tí ó jé àgùnbánirò, tí a mò sí Miss Chinda Uchechi Happiness, ni ó pàdánù èmí rè ní ojó kokàndílógún osù kokànlá (November 19) ...
Read More »Maryam Sanda ti sun ekún àsun-n-dáké nígbà tí won gbe lo sí ilé-ejó látàrí ikú tí ó se pa oko rè Billyaminu Bello.
Maryam Sanda tí won fi èsùn kàn wípé ó gún oko rè Bilyaminu Bello tí ó jé omo alága egbé PDP télè, Haliru Bello pa ní ilé won ní Abuja ní ojó àìkú (Sunday) tí ó kojá, ni ...
Read More »Arábìnrin yí se ayeye ojó-ìbí fún omo òdò rè ní àrà òtò.
Èyin obìnrin n’ílé, èèyàn mélòó ni ó le se eléyìí fún omo òdò rè. Omodé yí àti olówó rè rè é nínú àwòrán yí, àná ni ojó ìbí rè. E jòwó obìnrin mélòó ni ó tún le se èyí ...
Read More »Àwon òrébìnrin tí ó lóyún ní ìgba kan náà ni won ya àwòrán pèlú oyún won.
Àwon òrébìnrin tí ó lóyún ní ìgba kan náà ni won ya àwòrán pèlú oyún won. Eléyìí ma ti è wuni won sì rewà pèlú oyún won papò. Mo ro wípé oyún kìí mú àwon èlòmíràn rewà ni, bí ti ...
Read More »