Home / Art / Àṣà Oòduà / Jude Okoye tí ó jé ègbón àwon psquare ti rò wípé àsìkò ti tó kí òun sòrò lórí Aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè.

Jude Okoye tí ó jé ègbón àwon psquare ti rò wípé àsìkò ti tó kí òun sòrò lórí Aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè.

Ó ti dá àwon olólùfé won lóhùn lórí èro ayélujára (Instagram), Jude Okoye ti fi ogbón sòrò nípa aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè tí ó sí wípé òun kó ni olórí ebí won.
Ó ko síbè wípé.
“A le fi tipátipá mú Esin lo sí odò sùgbón a kò le fi tipátipá fun lómi mú”.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

yoruba culure

#Masoyinbo Episode Sixty-Three: Exciting Game Show Teaching Yoruba language and Culture.