Awon ibeji okunrin meji fe awon ibeji obirin kan naa.
Awon pasito meji to so won po, ibeji ni won.
Awon ore iyawo meji to tele won, ibeji ni won.
Awon omo iyawo obirin, ibeji ni won. Awon omo iyawo okunrin, ibeji ni awon naa.
Ilu India ni igbeyawo naa ti waye.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


